(Poem for marriage in yoruba)
Bayi ni ibagbepo Eyi mejeeji yo se beere.nígbà tí ẹ̀yin méjèèjì bá sọ ẹ̀jẹ́ yín,e o ṣe ileri lati lo gbogbo aye yin bi ọkan.Nitori ifẹ teni si ra yin.
Chorus: ELEDUMARE fun wa ni Ife,fu wa ni ebun omo jojolo,ki o se gba awon adura wa ninu igbeyawo yi.
Awa layika awon ayanfe wa,Ti won fere fun wa,ti won si n reti nnkan daradara lati o do wa,Lati gbe ni irepo ati ife.
Chorus:ELEDUMARE, Fun wa ni ife,fun wa ni ebun omo jojolo,ki o si gba awon adura wa ninu igbeyawo yi.
Gba ra re ni akoko lati fi gbe ni ojo oni,tori igbeyawo re ti beere,wo gbogbo ayika re, ki o si dunu fun akoko na.
Chorus: ELEDUMARE, Fun wa ni ife,fun wa ni ebun omo jojolo, ki o si gba awon adura wa ninu igbeyawo yi.
A o sọrọ nipa awọn iranti
Oun ti a ti ṣe papọ,Ati awọn akoko ti a ti jo pin tele ri,
Lati gbe pelu re titi lailai.
Chorus: ELEDUMARE, fun wa ni ife, fun wa ni ebun omo jojolo, ki o si gba awon adura wa ninu igbeyawo yi.
Mimo Mimo Ni Oluwa Olorun Eledumare
Iba fun Eledumare
Iba Ase