(Poem for father in yoruba)
Baba ni olori ebi,asiwaju idile, baba lo n gbo bukata olori omo,akoni lojo Ogun le,Eni ti kin fi igba kan simmi Ogun,baba mi ko jagun iko abi ibon,Ogun bo se ma fi ounje si ori tabili lo n ja.
Chorus: Baba ni jigi omo, baba ni ife akoko,baba ni olubadamoran, Eledumare,da baba si fun wa.
Ere bi ebi re o se ni mo inira,ti won ni kuna ikan rere lo n wa ka, ojojumo lo n fi ara gba ogbe loju gun,beni koje ki Ogun o sinmi.
Chorus: Baba ni jigi omo,baba ni ife akoko, baba ni olubadamoran, Eledumare, da baba si fun wa.
Baba ni ekun oko oke,kiniun oloju deru ba omo, ta lole gbe na woju re,kosi omo ti o tobe,kosi omo na tio fowo pa ida baba re loju.
Chorus: Baba ni jigi omo, baba ni ife akoko, baba ni olubadamoran, Eledumare, da baba si fun wa.
oni beru kan ti omo ni ni baba re je,baba ni iya mafi n derutba omo,ti omo ba gbo pe baba re n bo, ere loma mu wole ati lo soru tipatipa, iya ti baba je po pupo lori omo.
Chorus: Baba ni jigi omo, baba ni ife akoko, baba ni olubadamoran, Eledumare, da baba si fun wa.
Mimo Mimo Ni Oluwa Olorun Eledumare
Iba fun Eledumare
Iba Ase