Education 16
Poem For Education Olódùmarè àwa ọmọ rẹ dé, Láti wá kọ́ ẹ̀kọ́ lọ́dọ̀ Rẹ. Kọ́ wa láti mọ ìyàtọ̀ kádàrá, Àti àwọn ère àfọwọ́fà. Chorus: Alákóso-ayé jọ̀wọ́ kọ́ wa, Ìpilẹ̀ṣẹ̀ ẹ̀kọ́, odù ayérayé. Kí ni ilé-ìwé gíga, Bí kò sí ìmọ̀ Elédùmarè nibẹ? Kí ni kókó ìmọ̀ ìjìnlẹ̀, …
